Place cursor over chart elements to see labels

q – Epo, alosi ile-ijosin tikinse onigbagbo, alaganbagebe (Matteu 13:38, 15:8, 9) S – Akoko Wahala ti agbaye nigba ikore iyin-rere: Ipinya alikama at Epo (Matteu 13:30, 38:40, Ifihan 14:15, 18)

KOKORO SI AWORAN AWON IGBA

 Igba (Aseko Awon Opin)

A.  Aiye ti o tiwa – Iran Akoko (2 Peteru 3:6, Genesis 6:11-13)

B.  Aiye Buburu isinsinyii – Iran Ikeji (Galatia 1:4, 1 Johanu 5:19, Malaki 3:15)

C.  Aiye to nbo – Iran Keta (Heberu 2:5, 2 Peteru 3:13, Efesu 1:10)

D.  Baba nla mejila (ise awon Aposteli 7:8)

E.  Igba awon juu (Deuteronomy 7:6, Orin dafidi 147:19-20)

F.  Igba Iyin-rere (Marku 1:14-15, Ise awon aposteli 15:14, Matteu 24:14)

G.  Igba messia (1 Korinti 15:25, Ifihan 20:1-6)

H.  Awon igba to nbo (Efesu 2:7, 3:21)

f.  Akoko wahala Isreli nigba Ikore Ara Juu: Ipinya Alikama at Iyangbo (Luku 3:16-17).

S.  Akoko Wahala ti agbaye nigba ikore iyin-rere: Ipinya alikama at Epo (Matteu 13:30, 38:40, Ifihan 14:15, 18)

T.  Iku keji – igba die, pipinya aguntan, Ewure (Matteu 25:31-32, Ifihan 20:7-10, 14-15, 1 Korinti. 15:26)


Awon ila (Awon Igbese si ogo)

K.  Ipo ogo ti orun ati ojuse agbara (Filippi 2:9-11)(Ifihan 3:21)

L.  Ipo bibi ti emi (Johannu 3:8, 1 Johannu 3:2)

M.  Ipo atunbi nipa ti emi (Romu 12:1, Peteru 1:3-4)

N.  Ipo oju rere olorun (si eniyan) (Jakobu 2:23, 5:8-9,19)

P.  Ipo riri oju rere olorun (lefitiku 16:30, Heberu 9:7-10)

R.  Ipo ese ati iwa buburu (Romu 5:12, Isaiah 64:6, Romu 10:3)


Oke (Egbegbe Awon Eniyan)

a.  Adamu ni eda pipe (Genesisi 1:27,31)

b.  Isubu Adamu ati iru awon omo re, ki o to di kikun omi (Gen. 6:5)

c.  Ni Olukuluku awon eniti a kaye igbani (Romu 4:2-3, Esekieli 14:20, Heberu 11)

d.  Gbogbo eniyan lati ekun omi si igba messia Romu 5:12, 1 Johannu 5:19

e.  Isreali ti ara di idalare apere gegebi Orile-ede (Lefitiku 16:33-34, Heberu 10:1)


Kristi

g.  Jesu ni odun 30, oje eda pipe(Heberu10:5, Johannu1:29-32)

h.  Jesu eni abi nipa ti emi ni jodani (Matteu 28:18, Johannu 5:26)

i.  Jesu, jidide bi eni ti orun (Matteu 28:18, Johannu 5:26)

k.  Jesu 40 ojo lehin ajinde, ninu ogo ti orun (Ise awon Aposteli 1:19, Heberu 9:14)

l.  Jesu, ni gba iyin-rere, ojoko pelu baba lori ite (Heberu 6:20, 10:12, ifihan 3:21)


Kristiani ni igba iyein-rere

m.  Egbe awon atunbi nipa ti emi ti o wa di ajo – nla  (1 korinti 3:11, 15)

n.  Egbe awon atunbi nipa ti emi ti o di iyawo ninu Kristi (Romu 12:1-2, Peteru 2:9-10, Galatia 5:22-25)

p.  Awon onigbagbo, ti ko yara soto lekunrere (Marku 9:41, ise awon Aposteli 26:27-28, Matteu 22:14)

q.  Epo, alosi ile-ijosin tikinse onigbagbo, alaganbagebe (Matteu 13:38, 15:8, 9)

Ni sise Ikore igba iyinrere

r. Jesu, ni ipada bo re lekeji (Johannu 14:13, Tessalonika 4:16)

s. Agbo kekere, ya soto kuro lara babiloni (Ifihan 18:15) Tesalonika 4:16-17)

t. Opo eniyan kuna lati gba ere tio tayo (Ifihan 7:13-17, 1 Korinti 3:13,15)

u. Babiloni, Ijo tio ni oruko lasan, kuna: Awon kan seku lori ila N, awon toku jakule sisale (Ifihan 3:15-16, 16:19).

v. Babiloni, ipinle-ese agabangebe ijo oloruko lasan, jakule si ila R, pelu awon alaigbagbo (Ifihan 18:2, Matteu 24:51)

Ni Sise Igba Egberun Odun

w.  Kristi ti a se logo, ori ati ara (Ifihan 19:7, 21:2)

x.  Egbe ti Kristi ti a se logo, njoba (1 Johannu 3:2, Juda 14 Ifihan 3:21, 20:4, 6)

y.  Egbe Ajo nla (Orin dafidi 45:14, ifihan 7:9-10, 13-17,19:1)

z.  Isreali ti ara pada si ipo olokiki (Romu 11:25, sekariah 18:13-23)

W. Araiye pada si ipo pipe ati irepo pelu olorun (Ifihan 21:1-4 Isaiah 35)